Yoruba ni ṣun mọ ni laa mọ ìṣe ẹni, eeyan gbe okeere niyi, inu si jin, o ju ọrun lọ. Awọn owe yii lo n salaye iru ipo ti gbajumọ oṣere tiata kan, Olu Olowogemo, ti ọpọ eeyan mọ si Portable wa lonii ...